Lyrics & Audio : Iwo Leni owo - Dare Praise

0

Lyrics & Audio : Iwo Leni owo - Dare Praise 




Iwo Leni owo
Iwo Leni Aponle
Jesus Leni owo 
Eru re bami oh baba 2x

Solo

Gbogbo orun  Yin o
Awon ta aye juba oo
Imole nla ninu ogbun
Eledumare iye biye agba ye.

Iwo Leni owo
Iwo Leni Aponle
Jesus Leni owo 
Eru re bami oh baba 

Olore ala anu 
Alati leyin mini olore 4x


Post a Comment

0Comments
Post a Comment (0)